Nigbati iyawo mi sọ fun mi wipe ohun ti loyun, inu mi poruru bi ẹniti nyọ jabọ lati oke ọgbun. Bẹẹni, inu mi dun, ṣugbọn… ah Ọlọrun mi. Titọju ọmọ ṣa a wa fun awọn obi, abi.
Nitorina, nibiyi ni mo duro si, pẹlu oju-riran, ti mo si nlaagun gbo o bi akanṣe aworan ẹfẹ inu iwe, pẹlu awọn aami ibeere ti npooyi yika ori mi bi mo ti npese ara mi fun gbogbo itọju ati ojuṣe fun ẹda alaaye miiran yatọ si ologbo mi. Ojuṣe mi ni lati ri wipe eniyan
Show full text